Aare Buhari lola ti setan lati rin irin ajo lo si orilede Cote d’Ivoire fun ipade 5th European Union-African Union (EU-AU) Summit ni ilu Abidjan ni ojo kejidinlogun si ojo kokandinlogun osu kokanla odun 2017.
Opolopo eto lo ti wa nile fun ipade yi, ti awon Aare orilede Africa to ku na si ti pinu lati kora won jopo si ibi ipade na. Awon oro lori ilosiwaju gbogbo orilede adulawo, isuna ati abo ni won ti pinu lati fi oro jomi-toro oro le lori.

Comments
Post a Comment