Aare orilede nigba kan ri Goodluck Jonathan ati Senitor Ben Bruce ti ki gbajugbaja odomode olorin Wizkid ku ise latari ami eye MOBO ti won fi da lola.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Awon adari mejeji yi lo se awon atejade yi lati fi kan sara si ogbontarigi ati akinkanju odomode olorin fun akitiyan re lori orin kiko ni orilede Nigeria ati agbaye lapapo. Kare omo akin.
Comments
Post a Comment