Asita ibon (stray bullet) pa arakunrin kan ni ipinle Anambra.

Arakunrin kan ti oruko re nje Lotachukwu Nwagboso lo so emi re nu nibi eto isinku ojiseolorun Vitalis Ihemeje to waye ni  Alaife Umuaku Uli, ni ijoba ipinle  Ihiala ni ipinle Anambra. Isele na waye nigba ti olode adugbo kan eni ton gbiyanju lati wa okada re, to si ti gbagbe wipe ohun gbe ibon seyin. Lojiji ni ibon na yin to si pa arakunrin na lesekese.
Awon agbofinro tiwa bere iwadi lori oro na, ti won si tin gbiyanju lati mu arakunrin olode na.

Comments