Awako kan wako pa osise ajo FRSC kan ni ipinle Ondo.

Arakunrin Sehinde Abolusoro ikan ninu awon osise ajo FRSC ni awako kan wa oko pa ni ilu Akure ipinle Ondo loni.  Awon ti oro na se oju won so wipe arakunrin na eni ton dari oko loju opopona Ilesa si Akure ni awako na gba nigba ton gbiyanju lati ya fun oko ajagbe kan ni oju opopona na.

Comments