Awon adigunjale pa eyan meji ninu ikolu ti won se si ile ifowo pamo Diamond Bank towa ni ilu Okija, ipinle Anambra. +18
Ojo buruku esu gbomimu ni ojo kejidinlogbon osu kokanla je ni ilu Okija, ipinle Anambra niba ti awon adigunjale kan lo se ikolu si ile ifowopamo to wa ni ijoba ipinle Ihiala ni ipinle na. Awon ti oro na se oju won so wipe awon agbofinro ko ipa ribiribi lati dekun ikolu na, sugbon awon adigunjale na yin ibon pa awako kan ati odomode kunrin kan nibi ti won tin salo.
Comments
Post a Comment