Mr2kay eni to sese bo ninu ikolu lowo awon adigunjale, eleyi ti iwadi fi ye wa wipe ikan ninu awon akegbe re Burna Boy lo se okunfa re lo ti ra oko ayokele tuntun. Odomode kunrin na lo se afihan aworan yi lori ero ayelujara instagram lati fi dupe lowo Olorun ati lati fi kan sara si awon ololufe re fun atileyin won lojojumo.
Comments
Post a Comment