Oga agba ati alukoro fun ile ise olopa Dolapo Badmus ti setan lati se igbeyawo ni ojo kini osu kejila (Dec 1).



Arabirin Dolapo Badmus eni to je oga agba ati alukoro fun ile ise olopa lo se afihan wipe oun ti setan lati se igbeyawo pelu ololufe re ni ojo kini osu kejila odun yi.

Comments