Ijoba apapo pelu atileyin IOM (International Organization of Migration) ti ko ipa takuntakun lati ri wipe awon omo Nigeria ton se eru ni orilede Libya toto okòólénígba àti mẹwàá ti pada wale. Ni kete ti won de papako ofurufu Muritala Muhammed ni ipinle Eko ni awon omo egbe ajo NEMA ati NCFRMI (National Commission for Refugees, Migrants and
Internally Displaced Persons) tete gba oruko won sile, ti won si bere sini se itoju won pelu Ounje, ile ati owo kekere lati bere aye won pada.
Ijoba apapo orilede Nigeria labe idari Aare Muhamoodu Buhari ti wa pinu lati ko opolopo awon omo orilede yi to si wa ni ilu Libya pada wale.
Ijoba apapo orilede Nigeria labe idari Aare Muhamoodu Buhari ti wa pinu lati ko opolopo awon omo orilede yi to si wa ni ilu Libya pada wale.
Comments
Post a Comment