Omo oba orilede London, Harry ti setan lati gbe orebirin ati ololufe re Meghan Markle ni iyawo ni Nottingham Cottage ti Kensington Palace ni London. Omo oba na lo se afihan yi nigba ton ba awon akoroyin soro wipe idunu nla lo je fun ohun lati se igbeyawo pelu arabirin na. O so siwaju si wipe odun 2016 ni awon tin ba ere ife awon bo, ti awon si ti setan lati se igbeyawo awon ni odun 2018.
Comments
Post a Comment