Owo awon agbofinro ti ba arakunrin kan to lu iyawo re pa ni ipinle Eko.

Arakunrin osise banki omo odun mejilelogbon kan ti oruko re nje Olaoluwa Adejo ni awon agbofinro ipinle Eko ti fi si atimole nitoripe o lu iyawo re pa ni inu ile won ni agbegbe Peluola, Oworonshoki, ni  Bariga, ipinle Eko.
  Gege bi oro ti omo won, omokunrin omo odun marun so, o so wipe Baba ohun fi beliti na iya ohun, o sa ni ada, o si fun ni otapiapia mu. O so siwaju si nigba ton ba awon olopa soro wipe, iya ohun o se nkankan fun Baba ohun, ti baba ohun fi pa iya ohun.

Atejade oro ti omo na se ni yi ni ede geesi;
“My daddy beat my mummy with a belt; machete her here (shows arms), machete her here (shows legs). He used the belt on her here (points at face); forced my mummy to drink otapiapia (insecticide). My daddy took my mummy away.
My daddy said my mummy should get out of the house. My mummy said no. In the night, my daddy woke my mummy up and said, ‘Mosquito is too much, let me go and buy otapiapia’. My daddy forced my mummy to drink it. She shook her head. She vomited.

My daddy slapped my mummy. My mummy did not do anything to him. My daddy gave her one blow. My daddy kicked her. Small blood came out. My daddy slapped her, kicked her, machete her, blow her, and put otapiapia in her mouth and in the food,”

Awon agbofinro ti wa mu arakunrin yi, leyin igba to lo si ago olopa lati lo so wipe iyawo ohun ti gba mi ara re, to si tin gbiyanju lati lo sin arabirin na.  Iya  Maureen, so fun awon agbofinro wipe omo ohun ti kuro ni ile oko re ni nkan bi ojo marun seyin sugbon o pada lati lo se ayeye ojo ibi awon omo  re.

Comments