Awako ajagbe kan wa oko pa omo ise re ni ipinle Delta. +18
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Awako ajagbe kan ni opopona Sapele ni ipinle Delta lo sesi te ikan ninu awon omo ise re pa. Awon ti oro na se oju won so wipe isele na je kayefi fun awako na. Awon osise ajo FRSC ti wa gbe oku arakurin na lo si ite igboku si to wa ni ipinle na.
Comments
Post a Comment