Awon agbofinro ton soju ipinle Kogi lana mu awon odaran ati ajunigbe toto ogbon ni oju opopona Okene si Lokoja. Opolopo awon nkan ohun ija oloro ni won ri gba lowo awon odaran na. Agbenuso fun awon olopa ni ipinle na ogbeni Jimoh Moshood nigba ton ba awon akoroyin soro so wipe ara awon odaran na lo sokunfa bi won se ji Jose Machada ti won si gba emi re.
Iwadi ti bere lori oro na, won si ti pinu lati gbe won lo foju ba ile ejo lai pe.
Comments
Post a Comment