Awon aworan nibi ayeye igbeywo Oserekunrin Ken Erics.















Igbeyawo laarin oserekunrin Ken Erics ati ololufe re olojo pipe Onyi Adada waye ni ojo kejidinlogbon osu kejila ni ilu Enugwu-Ukwu, ni ipinle Anambra. Opolopo awon osere to peju sibe ni Rita Edochie, Zubby Michael, Ugezu j. Ugezu, maccolins chidebe, Rechael okonkwo, destiny etiko, Ngozi Ezeonu, Ebele okaro, Ony Michael, Jnr. Pope ati bebe lo.

Comments