Oni ni ayeye ojo ibi odunkejidinlogoji (38years) ti gbajugbaja oserekunrin Odunlade Adekola.



Oserekunrin Odunlade Adekola ninu afihan awon aworan ati atejade kan to se lori ero ayelujara instagram, fi idunu re han fun ore ofe to ri gba lati se ayeye ojo ibi odunkejidinlogoji re.  Atejade na ni yi ni ede geesi;

I am so much happy. As you celebrate me, the whole world will celebrate your glory with you in JESUS name. Happy birthday to your boy!'.

Comments