Owo awon agbofinro ba odaran kan nibi to tin gbiyanju lati ji batiri (battery) gbe.




Gege bi atejade ti ogbeni Chukwuebuka Oguejiofor se lori ero ayelujara Facebook owo awon agbofinro ba odaran kan nibi to tin gbiyanju lati ji batiri ti awon osise ile ise GLO n lo lati fi sise. Won ti fa arakunrin na le awon olopa lowo, won si ti bere iwadi lori esun na.

Comments