Eto isinku Ologbe Deji Tinubu.









Eto isinku ologbe Deji Tinubu eni to ku ni ojo karunlelogun osu kini odun yi loti bere loni ni ile ijosin City of David parish, RCCG Victoria Island ni ipinle Eko. Awon to peju sibi eto isinku na ni  Gomina ipinle Eko Akinwunmi Ambode ati iyawo re Bolanle, iyawo Aare orilede Nigeria Dolapo Osinbajo, gomina ipinle Ogun Ibikunle Amosun, ati ogbeni  Dele Momodu.

Comments