Ile ejo ni ilu Abuja da ejo egba fun arakunrin kan to ji apo ewa kan.

Ile ejo Karmo Grade 1 Area Court ni ilu Abuja ti dajo wipe ki won fun arakunrin akn ti oruko re nje Kabiru Badamasi ni egba mefa fun esun wipe o ji apo ewa kan ni adugbo Gwagwa Karmo. Adajo agba to dajo na  Abubakar Sadiq so wipe ohun kan sanu re ni latari wipe o so otoo o si bere fun aforiji.

Comments