Iya gbajugbaja olorin Olamide ti ku.


Odomodekunrin olorin na lo se afihan aworan ati atejade kan lori ero ayelujara instagram lati fi han wipe iya ohun ti ku.  Atejade oro to se ni wipe Orisa bi iya o si.

Comments