O ma se o!. Arabirin oloyun ati akeko ile iwe giga Gateway Polytechnic, Igbesa, ni ipinle Ogun so emi re nu nigba ton robi.












Odomodebirin ati akeko ile iwe giga Gateway Polytechnic, Igbesa, ipinle Ogun, Aaliyah Kennedy, ti so emi re nu nigba ton robi omo na. Arabirin na ati omo na ni won se alaisi. Ibanuje nla ni isele yi je fun awon molebi ati awon ore re, won si se opolopo atejade lori ero ayelujara Facebook lati ki pe odigba o se.

Comments