Opolopo awon eniyan lo farapa ninu ijamba nigba ti oko ajagbe kan rolu awon oko akero kan ni agbegbe oworonshoki ni ipinle Eko ni oni, ojo kokanlelogbon osu yi. Gbogbo awon to farapa ni awon eleyinju anu ti ko lo si ile iwosan, lati gba itoju to peye.
Comments
Post a Comment