Oserebirin Nora Nkiruka Ugo ti ku.




Oserebirin Nora Nkiruka Ugo ti ku. Gege bi iwadi, won so wipe iku arabirin na waye leyin aisan ranpe ninu opin ose to koja. Awon akegbe, molebi ati ore re si ti ki ku odigba o se lori ero ayelujara facebook ati instagram.

Comments