Aare Buhari se ipade pelu awon oluko ile iwe giga UNIMAID ti awon agbesunmomi Bokoharam sese tu sile.
Aare Mohamoodu Buhari loni se ipade pelu awon osise ile iwe giga UNIMAID meta ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ji gbe ni odun to koja, pelu awon obirin mewa ti won ji gbe ni odun to koja bakana. Ninu ipade na, Aare Buhari fi da won loju wipe ohun o ri wipe wo da awon omo ile eko Dapchi, ni ipinle Yobe ti awon odaran na tun sese ji ko pada si ile won ni alafia.
Comments
Post a Comment