Awon Fulani daran-daran mefa ni awon omoologun Nigeria mu ti won si pa mewa ninu won nni ilu Garigiji ipinle Adamawa. Eyi waye ninu ikolu to sele leyin igba ti awon ara ilu na ta awon omo ologun na ni ologbo wipe awon Fulani daran-daran na ti wa se ijamba ninu ilu won.
Ni kete ti awon omoologun na gbo eyi ni won lo si ilu na lati lo koju awon odaran na, ti won si segun won. Opolopo awon nkan ija oloro ni won gba lowo awon odaran na, ti won si ti fa won le awon agbofinro lowo.
Comments
Post a Comment