#BBNaija; Ogbeni Tobi ti dibo lati le arabirin Cee C kuro ninu idije Big Brother Naija. (MOMMY TOBI, E KU ISE O, Abiamo tooto).)
Iyalenu nla lo je nigba fun gbogbo awon oluworan idije Big Brother Naija loni nigba ti ogbeni Tobi dibo yan arabirin Cee C ati Lolu kuro ninu idije na, to si fi arabirin BamBam ati ogbeni Rico ropo re. Iyalenu na waye latari wipe ore ni awon mejeji je nigbakan ri ki ija to be sile laarin won.
Atejade ti awon oluworan idije na se lori oro na niyi lori ero ayelujara Twitter;
Atejade ti awon oluworan idije na se lori oro na niyi lori ero ayelujara Twitter;
Comments
Post a Comment