Buhari, Osinbajo, Okorocha, Oyegun, El-Rufai, Amosun, Bello. Shettima, Ambode, Akeredolu, Ortom, peju sibi ipade APC National Executive Committee meeting loni.
Ipade APC National Executive Committee (NEC) meeting to waye ni APC National Secretariat ni ilu Abuja loni ni awon agba oje ninu egbe oloselu na peju si. Awon to peju sibi ipade na ni APC National Chairman John Odigie Oyegun, Chairman APC Governor's Forum ati Gomina ipinle Imo St Rochas Okorocha ati APC National Women Leader Hajia Ramatu Tijani. Gomina Akinwunmi Ambode ti ipinle Eko, Nasir El-Rufai ti Kaduna, Ibikunle Amosin ti Ogun ati awon bebe lo.
Comments
Post a Comment