Captain Nurudeen Ogunlade. Afinju omo Oodua to mu idagbasoke wa si ipinle Osun.

Alase ati oludari ile ise AWOL international company, Captain Nurudeen Ogulade pelu ifowosowopo ijoba ipinle Osun ti setan lati se ifilole papako ofurufu MKO Abiola to wa ni ilu Osogbo ni ipinle Osun.  Nkan to joju, to si je nkan amu yangan ni eleyi je ni ipinle na.  Ojo aje, ojo kerin osu keta ni ojo ti ifilole papako ofurufu na yo waye.
 Idunu ati ayo ni awon omo ipinle omoluabi wa bayi latari idagbasoke ti Captain Nurudeen Ogunlade ati ijoba ipinle Osun labe idari Gomina ipinle na Ogbeni Rauf Aregbesola ti gbe wa si ipinle na.

Comments