Ninu afihan amohun-maworan kan ti Senato Ademola Adeleke se lori ero ayelujara instagram, o so wipe gbogbo ijo ti ohun ma n jo yen , wipe abinibi ni, o so siwaju si wipe orire ati ola ti Davido ati omo ohun Bred ni ko jo ohun loju nitoripe ohun ni ohun ko won bi won se n jo, ti won si se n korin.
Comments
Post a Comment