Aare Buhari ti setan lati lo se abewo si ipinle Eko.

Aare Buhari ninu afihan kan ti awon osise ijoba apapo se ti fi han wipe ohun o se abewo si ipinle Eko ni ojo kokandinlogbon osu keta.  Abewo yi o wa lati se ifilole ibudoko igbalode ti ijoba ipinle Eko labe isakoso ati idari Gomina Akinwumi Ambode.
   Leyin eyi, Aare Buhari o duro lati se ayeye ojobi agba oloselu ati adari egbe oloselu APC Bola Tinubu.

Comments