Awon agbofinro mu odaran kan pelu agbari eyan meta ni ilu Ilorin.

Awon olopa ton soju ipinle Kwara lana  mu odaran kan ti oruko re nje Suleiman Adenifuja ni oju opopona Eyenkorin si Ogbomoso pelu agbari eyan meta.
  Nigba ti won fi oro wa arakunrin na lenu wo, O so wipe ilu Eko ni ohun tin ko agbari na bo si ilu Ilorin.
 Oga olopa ipinle na Lawan Ado nigba ton ba awon akoroyin soro ro awon ara ilu na wipe ki won ma sora, ki won ma se afara lati fi oro to awon agbofinro leti nigbakugba ti won ba feti ko firi ijamba kankan.

Comments