Awon eyan meta lo ti ku ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri.

Awon omo egbe ajo National Emergency Management Agency (NEMA) ti fi han ninu atejade kan wipe awon omo egbe agbesunmomi bokoharam se akolu ni agbegbe Muna ni ilu Maiduguri ni ipinle Borno.
  Opolopo awon eyan lo so emi won nu ninu ikolu na ti awon miran si farapa yana-yana. 

Comments