Awon odaran pa awon omologun mokanla kan ni ilu Kaduna.

Awon omoologun Nigeria mokanla ni awon odaran kan pa ni ijoba ipinle Birnin Gwarini ipinle Kaduna. Awon omologun na ni won fi idi ise AYEM AKPATUMA ni ipinle na.
  Oruko awon omologun na ni;
1. Private Olabode Hammed
2. Private Bamidele Adekunke Emmanuel,
3. Private Onuchukwu Christian Chigoziri
4. Private Adamu Muhammed
5. Private Lamara Ahmed
6. Private Mubarak Suleiman,
7. Private Bashir Dani
8. Private Usman Abubakar Halo
9. Private Nafiu Iliyasu
10. Private Safiyanu Ahmed
11. Private Alhassan Ibrahim.
 Won ti sin oku awon omologun na si ite igbokusi  Commonwealth Cemetery ni Kaduna.

Comments