Awon olopa ton soju ipinle Kogi ti pinu lati fi Senator Dino Melaye si atimole.

Leyin isele to sele ni ogba ewon A' Divisionni Lokoja nibi ti awon odaran mefa ti sa kuro ninu ogba ewon na ni awon agbofinro ati awon olopa ipinle Kogi ti pinu lati ti Senato na mole.
 Ninu atejade ti oga olopa ipinle na CP Ali Janga se, o so wipe ibikibi ti ohun ba ti ri Dino Melaye ati omo Gomina ipinle Kogi nigba kan ri, Abubakar Audu ni awon o ti won mole.

Atejade to se ni yi ni ede geesi;

''Consequently, all the six suspects, Senator Dino Melaye and Mohammed Audu were sent for watch listing and red notice by the INTERPOL for immediate arrest any where we see them. The Command hereby appealed to the members of the public to assist the Police with useful information on the whereabouts of the suspects by reporting to the nearest Police Station.

Comments