Awon omoegbe okunkun kan se iku pa akeko ile eko giga Ambrose Alli.




Odomodekunrin akeko kan omo odun metadinlogbon kan ti oruko re nje Emmanuel Onaghise, ni awon omo egbe okunkun kan se iku pa loni ni agbegbe Obalende ni ipinle Eko.
  Awon agbofinro wayi ti bere iwadi to peye lori oro na, won si ti pinu lati mu awon odaran na.

Comments