Aworan ayeye ojo ibi Col. Mohammed Lawal Abubakar.







Awon omo Aare Buhari Zahra, Yusuf ati Halima lana dijo gbero ayeye ranpe fun ikan lara awon osise baba won Col. Mohammed Lawal. Ayeye na waye ni inu ile ijoba to wa ni ilu Abuja.

Comments