#BBNAIJA. Odomodebirin BAMBAM ti ja kuro ninu idije BigbrotherNaija. (ogbeni Teddy-A, e ku araferakun)

Iyalenu nla lo je loni nigba ti awon oludije ninu idije BBN se o digba o se si ikan ninu awon akegbe won, arabirn BAMBAM, leyin igba ti awon oludije na se ayeye opin ose won tan.
  Wayi, arabirin BAMBAM ti lo ba awon akegbe re yoku bi Leo, Ifu Enada ,Angel, Ahneeka, Bitto, Princess, Dee-One ati Vandora.   O ma se o.

Comments