Iko egbe agbaboolu orilede Serbia na egbe agbaboolu Super eagles ni omi ayo meji si odo (2-0)

Ninu ifesewonse boolu alasefe gba to waye laarin egbe agbaboolu Serbia ati agbaboolu Super eagles ni ilu London la'na ni iko egbe agbaboolu Serbia ti gba omi ayo meji si odo wole ti egbe agbaboolu super eagles o si ri ikankan da pada.

Comments