Ile ejo ti da ejo iku fun Oloye kan ni ipinle Delta.

Ile ejo kan to wa ni ipinle Delta ti da ejo iku fun Oloye Newton Agbofodo eni to je ikan ninu awon oloye Ekpan, ijoba ipinle Uvwie Council Area.
 Idajo na waye latari esun ipaniyan, ati esun adigunjale to waye ni  Delta Mallni osu kini odun 2018. Awon agbofinro ati adajo na fi opolopo esun kan oloye na, ti won si wadi wipe o jebi gbogbo awon esun na.

Comments