Ile iwe giga Unifasiti ti Ibadan ti setan lati le awon akeko kan latari wipe won o dangajia to lenu eko won.
Awon alakoso ile iwe giga Unifasiti ti Ibadan ninu atejade kan ti won se ti pinu lati le awon akeko melo kan latari ai dangajia to lenu eko won.
Alakoso agba ni ile iwe giga na, Prof. Idowu Olayinka nigba ton ba awon akoroyin soro so wipe idi to fa ai sedede to awon akeko na ni wipe awon akeko na o se idanwo post UTME.
O so siwaju si wipe idojuti nla lo je fun gbogbo awon akeko na ati awon oluko ile eko giga na la'papo.

Comments
Post a Comment