Oga agba pata-pata awon olopa Ibrahim Idris, ti da oga olopa ipinle Kogi, Ali Janga duro.

Oga agba pata-pata awon olopa Ibrahim Idris loni ti pase lati da oga olopa ipinle Kogi Ali Janga duro.
  Idaduro na waye leyin bi wakati meji ti awon odaran sa jade kuro ninu atimole awon olopa ni ipinle Kogi.  Iwadi to peye ti wa n lo lori bi won o se ri awon odaran na mu pada.

Comments