Ogbeni Femi Fani Kayode ninu atejade kan to se lori ero ayelujara twitter ti fi enu abuku kan igbakeji Aare Yemi Osinbajo. O kan labuku nigba to pe ni Opuro, Adojutini ati alai-lojuti. Eyi waye leyin igba ti Yemi Osinbajo fi enu ete kan egbe oloselu PDP nibi apeje ti Asiwaju Bola Tinubu.
Comments
Post a Comment