Owo awon agbofinro ti ba marun ninu awon odaran mefa to sa lo ni atimole awon olopa ni ipile Kogi.

Awon agbofinro ton soju ipinle Kogi ti mu marun ninu awon odaran mefa to salo ni atimole awon olopa ni ojo kejidinlogbon osu yi ni ilu Lokoja.
  Gege bi iroyin to ti ile iroyin Sahara reporters jade, won so wipe awon marun yi ni won ajosepo pelu Seneto Dino Melaye.

Comments