Owo ton da eru ba osi ni won fun mi ni ibi ayeye igbeyawo Fatima Dangote. Ogbeni Swanky Jerry lo so be.


Ninu atejade kan ti ogbeni Jeremiah Ogbodo eni ti gbogbo eyan mo si Swanky Jerry se lori ero ayelujara instagram. O fi han wipe owo ton deru ba osi ni won fun ohun fun ise ti ohun se nibi ayeye igbeyawo Fatima Dangote ati oko re Jamil Abubakar.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

"If I say how much I was paid on this job now people will say I'm bragging...... but hey it was my pleasure ...... #famil2018 NOTE THAT I WAS PAID MORE THAN ENOUGH TO FLY IN THE BIGGEST HOLLYWOOD STYLIST SO MUCH MORE .. MUCH MORE

Comments