Aare Buhari loni ti de de ilu Washinton ni orilede America fun igbaradi ipade re pelu Aare orilede America, Donald Trump ti yo waye ni ogbon ojo osu kerin. Opolopo awon ogbontarigi eyan ati awon afinju onisowo bi Aliko Dangote ati awon bebe lo, lo tele Aare na lati lo se ipade yi.
Comments
Post a Comment