Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki lo se abewo si awon agunbaniro to wa ni ipinle Kwara






Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki loni lo se abewo si odo awon agunbaniro to wa ni ipinle Kwara leyin iroyin ikan ninu won omidan Hilda Eva Amadi to emi re nu. Igbakeji Aare na lo fi ibanuje re han lori oro na, to si ba awon obi ati alamojuto omo na kedun fun iku omo na.

Comments