Isele kayefi kan sele ni ilu Ozzu Awkuzu ni ijoba ipinle Oyi ni ipinle Anambra nigba ti arakunrin kan gba emi omo Ikibunna Udeagu re lori ija ati awo ti won ni lori ile kan. Awon agbofinro ti wa bere iwadi lori oro na, won si ti gbe oku odomode kunrin na lo si ite igboku si.
Comments
Post a Comment