Awon agbebon kan ji agba egbe oloselu PDP gbe ni ipinle Ekiti

Awon agbebon kan ti ji agba oje ninu egbe oloselu PDP Kayode Oni gbe ni ipinle Ekiti. Opopona Efon Alaaye-Erio-Ekiti ni won ti gbe arakunrin na. Iroyin fi to wa leti wipe ona ilu re ni Aramoko Ekiti ni won ti gbe arakunrin na.

Atejade ti won agbenuso re Jackson Adebayo se ni yi ni ede geesi;

“He went to conduct our local government congress in Efon Alaaye and he was abducted while returning to Aramoko. The family had been contacted, but they told the abductors that even the entire family can’t raise N1 million and they were requesting for a staggering sum of N30 million to secure his freedom. The family told us reliably that it had made a formal complaint at the police station in Efon about the situation and they promised to take action. Our party is not resting as well. We are making contacts to ensure that his safety is guaranteed in the kidnappers’ den.”

Comments