Awon jangduku kan lo da ina sun ile ise ajo INEC ni ipinle Rivers


Ile ise ajo INEC Rivers State Independent Electoral Commission (RISEC) to wa ni agbegbe Bori ijoba ipinle Khana ni awon janduku kan ti do da ina sun loni, ojo ketadinlogbon osu kerin. Iwadi fi ye wa wipe ikolu na waye latari eto idibo ton bo lona ni ipinle na.
 Iwadi to peye ti wan lo lori ikolu na ti awon agbofinro si ti pinu lati fi oju awon koloransi na gun igi.

Comments

Post a Comment