Awon omo leyin Krisiti to wa ni ipinle Benue se iwode ita gban-gba latari ipaniyan ojojumo ton sele ni ipinle na
Agbajopo egbe awon omo leyin Kristi to wa ni ipinle Benue CAN ni ose to koja ro gbogbo awon Kristeni to wa ni orilede Nigeria lati jade ki won si se iwode ita gban-gba latari ipaniyan ati ikolu ti awon oni ija esin n se si awon Kristeni ni ipinle Benue.
Iwode na da lori ebe si Aare Buhari lati wa woroko fi se ada lori oro na ki wahala to ju bayi lo to bere sini sele.
Comments
Post a Comment