Gbajugbaja odomode olorin Davido ra oko ayokele Porshe fun Chioma ololufe re lati fi se ayeye ojo ibi re
Odomode kunrin olorin omo baba olowo David Adeleke, eniti inagi re n je Davido loni fi oko ayokele Porshe da ololufe re Chioma lola lati fi se ayeye ayajo ojo ibi odun ketalelogun arabirin na.
Iwadi fi ye wa wipe ife alai-legbe lon joba laarin awon ololufe mejeji na ti won si ti pinu lati gbe ara won ni iyawo.
Comments
Post a Comment