Ijoba apapo ti mu ojo kini osu karun gege bi ojo isimi lati fi se ayeye ayajo awon osise.
Lt Gen. Abdulrahman Dambazau eni to se atejade yi, ki awon osise Nigeria ku ifarada ati akitiya lati gbe orilede Nigeria doke laarin awon orilede to wa ni agbaye.
Comments
Post a Comment